Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kọ́ríńtì 6:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìrẹ́pọ̀ kín ni tẹ́ḿpìlì Ọlọ́run ní pẹ̀lú òrìṣà? Nítorí ẹ̀yin ní tẹ́ḿpìlì Ọlọ́run alààyè; gẹ́gẹ́ bí Ọlọ́run ti wí pé, “Èmi á gbé inú wọn, èmi o sì máa rìn láàárin wọn; èmi ó sì jẹ́ Ọlọ́run wọn, wọn yóò sì jẹ́ ènìyàn mi.”

Ka pipe ipin 2 Kọ́ríńtì 6

Wo 2 Kọ́ríńtì 6:16 ni o tọ