Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kọ́ríńtì 6:1-3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Gẹ́gẹ́ bí alábáṣiṣẹ́ pọ̀ nínú Ọlọ́run, ǹjẹ́, àwa ń rọ̀ yín kí ẹ má ṣe gba oore ọ̀fẹ́ Ọlọ́run lásán.

2. Nítorí o wí pé,“Ní àkókò ìtẹ́wọ́gbà mi, èmi tí gbọ́ ohùn rẹ,àti ọjọ́ ìgbàlà, èmi sì ti ràn ọ́ lọ́wọ́.”Èmi wí fún ọ, nísínsín yìí ní àkókò ìtẹ́wọ́gbà, nísínsín yìí ní ni ọjọ́ ìgbàlà.

3. Àwa kò sì gbé ohun ìkọ̀sẹ̀ kankan si ọ̀nà ẹnikẹ́ni, ki iṣẹ́ ìránṣẹ́ wa má ṣe di ìsọ̀rọ̀ òdì sí.

Ka pipe ipin 2 Kọ́ríńtì 6