Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kọ́ríńtì 6:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n dípò bẹ́ẹ̀, ni ọnà gbogbo, àwa ń fí ara wa hàn bí àwọn ìránṣẹ́ Ọlọ́run nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ sùúrù, nínú ìpọ́njú, nínú àìní, nínú wàhálà,

Ka pipe ipin 2 Kọ́ríńtì 6

Wo 2 Kọ́ríńtì 6:4 ni o tọ