Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kọ́ríńtì 5:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí náà àwa ni ikọ̀ fún Kírísítì, bí ẹni pé Ọlọ́run ń ti ọ̀dọ̀ wa ṣìpẹ̀ fún yín: àwa ń bẹ̀ yín nípò Kírísítì, “Ẹ bá Ọlọ́run làjà,”

Ka pipe ipin 2 Kọ́ríńtì 5

Wo 2 Kọ́ríńtì 5:20 ni o tọ