Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kọ́ríńtì 5:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èyí ni pé, Ọlọ́run wà nínú Kírísítì, ó ń bá aráyé làjà sọ́dọ̀ ara rẹ̀, kò sí ka ìrékọjá wọn sí wọn lọ́rùn; ó sì ti fi ọ̀rọ̀ ìlàjà lé wa lọ́wọ́.

Ka pipe ipin 2 Kọ́ríńtì 5

Wo 2 Kọ́ríńtì 5:19 ni o tọ