Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kọ́ríńtì 13:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ máa wádìí ara yín, bí ẹ̀yin bá wà nínú ìgbàgbọ́; ẹ máa dán ara yín wò. Tàbí ẹ̀yin fúnra yín kò mọ ara yín pé Jésù Kírísítì wá nínú yín? Àfi bí ẹ̀yin bá jẹ́ àwọn tí a tanù.

Ka pipe ipin 2 Kọ́ríńtì 13

Wo 2 Kọ́ríńtì 13:5 ni o tọ