Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kọ́ríńtì 13:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí pé a kàn án mọ́ àgbélébùú nípa àìlera, ṣùgbọ́n òun wà láàyè nípa agbára Ọlọ́run. Nítorí àwa pẹ̀lú já sí aláìlera nínú rẹ̀, ṣùgbọ́n àwa yóò wà láàyè pẹ̀lú rẹ̀ nípa agbára Ọlọ́run sí yín.

Ka pipe ipin 2 Kọ́ríńtì 13

Wo 2 Kọ́ríńtì 13:4 ni o tọ