Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Tẹsalóníkà 5:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní àkókò gan an tí àwọn ènìyàn yóò máa wí pé, “Àláfíà àti àbò,” nígbà náà ni ìparun òjijì yóò dé sórí wọn gẹ́gẹ́ bí ìrọbí obìnrin tí ó lóyún, wọn kò sí rí ibi ààbò láti sá sí.

Ka pipe ipin 1 Tẹsalóníkà 5

Wo 1 Tẹsalóníkà 5:3 ni o tọ