Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Pétérù 5:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ máa tọ́jú agbo Ọlọ́run tí ń bẹ láàrin yín, ẹ máa bojútó o, kì í ṣe àfipáse, bí kò se tìfẹ́tìfẹ́; kó má sì jẹ́ fún èrè ijẹkújẹ, bí kò ṣe pẹ̀lú ìyè inú tí ó múra tan.

Ka pipe ipin 1 Pétérù 5

Wo 1 Pétérù 5:2 ni o tọ