Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Pétérù 5:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn alàgbà tí ń bẹ láàrin yín ni mo gbànímọ̀ràn, èmi ẹni tí ń ṣe alàgbà bí ẹ̀yin, àti ẹlẹ́rìí ìyà Kírísítì, àti alábàápín nínú ògo tí a ó fihàn:

Ka pipe ipin 1 Pétérù 5

Wo 1 Pétérù 5:1 ni o tọ