Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Pétérù 2:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

àti pẹ̀lú,“Òkúta ìdìgbòlù,àti àpáta ìkọ̀sẹ̀.”Nítorí wọn kọsẹ̀ nípa ṣíṣe àìgbọ́ràn sí ọ̀rọ̀ náà, sínú èyí tí a gbé yàn wọ́n sí pẹ̀lú.

Ka pipe ipin 1 Pétérù 2

Wo 1 Pétérù 2:8 ni o tọ