Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Pétérù 2:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹni, nígbà tí a kẹ́gàn rẹ̀, tí kò sì padà kẹ́gàn; nígbà tí ó jìyà tí kò sì halẹ̀; ṣùgbọ́n ó fi ọ̀ràn rẹ̀ lé ẹni ti ń ṣe ìdájọ́ òdodo lọ́wọ́.

Ka pipe ipin 1 Pétérù 2

Wo 1 Pétérù 2:23 ni o tọ