Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kọ́ríńtì 2:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bẹ́ẹ̀ kọ́, àwa ń sọ̀rọ̀ ọgbọ́n ti Ọlọ́run tó farasin, ọgbọ́n tí ó ti farapamọ́, èyí tí Ọlọ́run ti lànà sílẹ̀ ṣáájú ìpìlẹ̀ṣẹ̀ ayé fún ògo wa.

Ka pipe ipin 1 Kọ́ríńtì 2

Wo 1 Kọ́ríńtì 2:7 ni o tọ