Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kọ́ríńtì 2:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n àwa ń sọ̀rọ̀ ọgbọ́n láàrin àwọn tí a pè; ṣùgbọ́n kì í ṣe ọgbọ́n ti ayé yìí tàbí ti àwọn olórí ayé yìí, èyí tí yóò di asán

Ka pipe ipin 1 Kọ́ríńtì 2

Wo 1 Kọ́ríńtì 2:6 ni o tọ