Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kọ́ríńtì 2:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí ìgbàgbọ́ yín kí ó má ṣe dúró lórí ọgbọ́n ènìyàn, ṣùgbọ́n kí ó dúró lórí agbára Ọlọ́run.

Ka pipe ipin 1 Kọ́ríńtì 2

Wo 1 Kọ́ríńtì 2:5 ni o tọ