Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kọ́ríńtì 12:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn ẹ̀yà ara tí ó dàbí ẹni pé wọ́n ṣe aláìlágbára jùlọ, tí ó dàbí ẹni pé kò ṣe pàtàkì rárá, àwọn gan-an ni a ko le ṣe aláìnílò.

Ka pipe ipin 1 Kọ́ríńtì 12

Wo 1 Kọ́ríńtì 12:22 ni o tọ