Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kọ́ríńtì 12:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí ó tí rí yìí, ojú kò lè sọ fún ọwọ́ pé, “Èmi kò nílò rẹ.” Bẹ́ẹ̀ ni orí kò le sọ fún ẹsẹ̀ pé, “Èmi kò nílò rẹ.”

Ka pipe ipin 1 Kọ́ríńtì 12

Wo 1 Kọ́ríńtì 12:21 ni o tọ