Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kọ́ríńtì 12:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bẹ́ẹ̀ ni ẹ̀yà ara ti a rò pé kò lọ́lá rárá ni àwa ń fi ọlá fún jùlọ. Àwọn ẹ̀yà ara ti a rò pé yẹ rára ni àwa ń fi ipò ẹ̀yẹ tí ó ga jùlọ.

Ka pipe ipin 1 Kọ́ríńtì 12

Wo 1 Kọ́ríńtì 12:23 ni o tọ