Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kọ́ríńtì 12:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó fi agbára fún àwọn mìíràn láti ṣe àwọn iṣẹ́ ìyanu. Ó fún àwọn mìíràn lágbára láti sọ àsọtẹ́lẹ̀ àti láti wàásù pẹ̀lú ìmísí. Bákan náà ló fún àwọn kan lẹ́bùn láti mọ ìyàtọ̀ láàrin àwọn Ẹ̀mí. Ó fún àwọn ẹlòmíràn ní ẹ̀bùn àti agbára láti lè sọ èdè tí wọn kò mọ̀ tí wọn kò rí. Bákan náà ó fún àwọn ẹlòmíràn lágbára láti mọ̀ àti láti túmọ̀ èdè tí wọn kò gbọ́ rí.

Ka pipe ipin 1 Kọ́ríńtì 12

Wo 1 Kọ́ríńtì 12:10 ni o tọ