Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kọ́ríńtì 12:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó fi ẹ̀bùn ìgbàgbọ́ fún ẹlòmíràn, ẹlòmíràn ló sì fi agbára ìwonisàn fún nípa Ẹ̀mí Mímọ́ kan náà.

Ka pipe ipin 1 Kọ́ríńtì 12

Wo 1 Kọ́ríńtì 12:9 ni o tọ