Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kọ́ríńtì 12:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àní, Ẹ̀mi kan ṣoṣo ní ń fún ni ní gbogbo ẹ̀bùn àti agbára wọ̀nyí. Òun ni ẹni tí ń ṣe ìpinnu ẹ̀bùn tí ó yẹ láti fún ẹnìkọ̀ọ̀kan.

Ka pipe ipin 1 Kọ́ríńtì 12

Wo 1 Kọ́ríńtì 12:11 ni o tọ