Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kọ́ríńtì 11:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí tí ẹ bá jẹ lára àkàrà, tí ẹ sì mu nínú kọ́ọ̀bù láìyẹ, tí ẹ kò ronú ara Kírísítì áti nǹkan tí ó túmọ̀ sí, ẹ̀ ń jẹ, ẹ sì ń mú ẹ̀bi ìdájọ́ Ọlọ́run wá sórí ara yín.

Ka pipe ipin 1 Kọ́ríńtì 11

Wo 1 Kọ́ríńtì 11:29 ni o tọ