Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kọ́ríńtì 1:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo bẹ̀ yín ẹ̀yin ara, ní orúkọ Olúwa wa Jésù Kírísítì, pé kí gbogbo yín fohùnsọ̀kan kí ó máa ṣe sí ìyàpá láàrin yín, àtipé kí a lè ṣe yín pé ní inú àti ìmọ̀ kan náà.

Ka pipe ipin 1 Kọ́ríńtì 1

Wo 1 Kọ́ríńtì 1:10 ni o tọ