Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Jòhánù 2:10-12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

10. Ẹni tí o ba fẹ́ràn arákùnrin rẹ̀, o ń gbé inú ìmọ́lẹ̀, kò sì sí ohun ìkọ̀sẹ̀ kan nínú rẹ̀.

11. Ṣùgbọ́n ẹni tí o bá kóríra arákùnrin rẹ̀ ń gbé nínú òkunkùn, ó sì ń rìn nínú òkùnkùn; kò sì mọ ibi tí òun ń lọ, nítorí tí òkùnkùn tí fọ́ ọ lójú.

12. Èmi ń kọ̀wé sí yín, ẹ̀yin ọmọ mi ọ̀wọ́n,nítorí tí a darí ẹ̀ṣẹ̀ yín jì yín nítorí orúkọ rẹ̀.

Ka pipe ipin 1 Jòhánù 2