Ṣùgbọ́n ẹni tí o bá kóríra arákùnrin rẹ̀ ń gbé nínú òkunkùn, ó sì ń rìn nínú òkùnkùn; kò sì mọ ibi tí òun ń lọ, nítorí tí òkùnkùn tí fọ́ ọ lójú.