Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Jòhánù 2:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi ń kọ̀wé sí yín, ẹ̀yin baba,nítorí tí ẹ̀yin tí mọ ẹni tí ó wà ní àtètèkọ́ṣe,Èmi ń kọ̀wé sí yín, ẹ̀yin ọ̀dọ́mọkùnrin,nítorí tí ẹ̀yin ti ṣẹ́gun ẹni ibi náà.Èmi ń kọ̀wé sí yín, ẹ̀yin ọmọdé mi ọ̀wọ́n,nítorí ẹ̀yin ti mọ Baba.

Ka pipe ipin 1 Jòhánù 2

Wo 1 Jòhánù 2:13 ni o tọ