Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sekaráyà 13:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n òun o wí pé, ‘Èmi kí í ṣe wòlíì, àgbẹ̀ ni èmi; nítorí tí a ti fi mí ṣe ìránṣẹ́ láti ìgbà èwe mi wá.’

Ka pipe ipin Sekaráyà 13

Wo Sekaráyà 13:5 ni o tọ