Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sekaráyà 13:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Yóò sì ṣe ní ọjọ́ náà, ojú yóò tí àwọn wòlíì èké olúkúlúkù nítorí ìran rẹ̀, nígbà tí òun ba tí ṣọtẹ́lẹ̀; bẹ́ẹ̀ ni wọn kì yóò sì wọ aṣọ wòlíì onírun rẹ̀ tí o fi ń tan ní jẹ.

Ka pipe ipin Sekaráyà 13

Wo Sekaráyà 13:4 ni o tọ