Éfúráímù yóò sì ṣe bí alágbára,ọkàn wọn yóò sì yọ̀ bi ẹni pé nípa ọtí-wáìnì:àní àwọn ọmọ wọn yóò rí í,wọn o sì yọ̀, inú wọn ó sì dùn nínú Olúwa.