Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sekaráyà 10:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Èmi o sì mú ilé Júdà ní agbára,èmi o sì gba ilé Jósẹ́fù là,èmi ó sì tún mú wọn padànítorí mo tí ṣàánú fún wọn,ó sì dàbí ẹni pé èmi kò ì tìí ta wọ́n nù;nítorí èmi ni Olúwa Ọlọ́run wọn,èmi o sì gbọ́ ti wọn

Ka pipe ipin Sekaráyà 10

Wo Sekaráyà 10:6 ni o tọ