“Ìbínú mi ru sí àwọn darandaran,èmi o sì jẹ àwọn olórí níyànítorí Olúwa àwọn ọmọ-ogun ti bẹ agbo rẹ̀,ilé Júdà wò,yóò ṣi fi wọn ṣe ẹṣin rẹ̀ dáradára ní ogun.