Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sekaráyà 10:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí àwọn òrìṣà tí sọ̀rọ̀ asán,àwọn aláfọ̀ṣẹ sì tí rí èké,wọn sì tí rọ àlá èké;wọ́n ń tu ni nínú láṣán,nítorí náà àwọn ènìyàn náà ṣáko lọ bí àgùntàn,a ṣẹ wọn níṣẹ̀ẹ́, nítorí Olùṣọ́àgùntàn kò sí.

Ka pipe ipin Sekaráyà 10

Wo Sekaráyà 10:2 ni o tọ