Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 52:1-4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Èéṣé tí ìwọ fi ń ṣe féfé nínú ìwà ìkà,ìwọ alágbára ọkùnrin?Oore Ọlọ́run dúró pẹ́ títí

2. Ahọ́n Rẹ̀ ń gbìmọ̀ ìparun;ó dà bí abẹ mímú,ìwọ ẹni tí ń hùwà ìrẹ́jẹ.

3. Ìwọ fẹ́ràn ibi ju ire lọ,àti èké ju kí ó sọ òtítọ́ lọ.

4. Ìwọ fẹ́ràn ọ̀rọ̀ ìpanilára gbogbo,ìwọ ahọ́n ẹ̀tàn!

Ka pipe ipin Sáàmù 52