Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sáàmù 52:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọlọ́run yóò sì lù ọ́ bolẹ̀ láéláé,yóò sì dì ọ́ mú,yóò sì já ọ kúrò ni ibùjókòó Rẹyóò sì fà ọ́ tu kúrò lórí ilẹ̀ alààyè. Sela

Ka pipe ipin Sáàmù 52

Wo Sáàmù 52:5 ni o tọ