Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Rúùtù 3:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Rí í dájú pé o mọ ibi tí ó sùn sí, lẹ́yìn ìgbà tí ó bá ti sùn, lọ kí o sí aṣọ ìbora rẹ̀ níbi ẹsẹ̀ rẹ̀ sókè kí o sì sùn síbi ẹsẹ̀ náà. Òun yóò sì sọ ohun tí ìwọ yóò ṣe fún ọ.”

Ka pipe ipin Rúùtù 3

Wo Rúùtù 3:4 ni o tọ