Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Orin Sólómónì 3:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó fi fàdákà ṣe òpó rẹ̀Ó fi wúrà ṣe ibi ẹ̀yìn rẹ̀Ó fi elésè àlùkò ṣe ibùjókòó rẹ̀,Inú rẹ̀ ni ó kọ àwọn ọ̀rọ̀ ìfẹ́ wọ̀nyí sí“Pẹ̀lú ìfẹ́ láti ọ̀dọ̀ àwọn ọmọbìnrin Jérúsálẹ́mù.”

Ka pipe ipin Orin Sólómónì 3

Wo Orin Sólómónì 3:10 ni o tọ