Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Oníwàásù 12:1-4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Rántí Ẹlẹ́dàá rẹní ọjọ́ èwe rẹ,nígbà tí ọjọ́ ibi kò tíì déàti tí ọdún kò tíì ní ṣun mọ́ etílé, nígbà tí ìwọ yóò wí pé,“Èmi kò ní ìdùnnú nínú wọn”

2. Kí oòrùn àti ìmọ́lẹ̀àti òṣùpá àti àwọn ìràwọ̀ tó ṣókùnkùn,àti kí àwọ̀ṣánmọ̀ tó padà lẹ́yìn òjò;

3. Nígbà tí olùṣọ́ ilé yóò wárìrìtí àwọn ọkùnrin alágbára yóò tẹríba,nígbà tí àwọn tí ó ń lọ̀ dá kẹ́ nítorí pé wọn kò pọ̀,tí àwọn tí ń wo òde láti ojú fèrèsé yóò ṣókùnkùn;

4. Nígbà tí ilẹ̀kùn sí ìgboro yóò tìtí ariwo ọlọ yóò dákẹ́;nígbà tí àwọn ènìyàn yóò dìde sí ariwo àwọn ẹyẹṣùgbọ́n gbogbo orin wọn yóò máa lọ ilẹ̀.

Ka pipe ipin Oníwàásù 12