Nígbà tí ilẹ̀kùn sí ìgboro yóò tìtí ariwo ọlọ yóò dákẹ́;nígbà tí àwọn ènìyàn yóò dìde sí ariwo àwọn ẹyẹṣùgbọ́n gbogbo orin wọn yóò máa lọ ilẹ̀.