Nígbà tí olùṣọ́ ilé yóò wárìrìtí àwọn ọkùnrin alágbára yóò tẹríba,nígbà tí àwọn tí ó ń lọ̀ dá kẹ́ nítorí pé wọn kò pọ̀,tí àwọn tí ń wo òde láti ojú fèrèsé yóò ṣókùnkùn;