Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Onídájọ́ 7:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa wí fún Gídíónì pé, “Àwọn ọmọ ogun tí o kó jọ sọ́dọ̀ ti pọ̀ jù fún mi láti fi àwọn ogun Mídíánì lé wọn lọ́wọ́, kí Ísírẹ́lì má ba à gbé ara rẹ̀ ga sí mi wí pé agbára òun ni ó gbà á là,

Ka pipe ipin Onídájọ́ 7

Wo Onídájọ́ 7:2 ni o tọ