Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Onídájọ́ 7:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

sì kéde sí àwọn ènìyàn nísinsìn yìí pé, ‘Ẹnikẹ́ni tí ó bá ń gbọ̀n, tí ó sì ń bẹ̀rù lè padà sẹ́yìn, kí ó sì kúrò lórí òkè Gílíádì.’ ” Báyìí ni Gídíónì ṣe ya àwọn ènìyàn náà. Ẹgbẹ̀rúnméjìlélógún ọkùnrin sì padà sẹ́yìn àwọn ẹgbẹ̀rún mẹ́wàá sì dúró.

Ka pipe ipin Onídájọ́ 7

Wo Onídájọ́ 7:3 ni o tọ