Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Onídájọ́ 7:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní òwúrọ̀ kùtùkùtù Jérúb-báálì (èyí ni Gídíónì) pẹ̀lú gbogbo àwọn ọmọ ogun tí ó wà pẹ̀lú rẹ̀ kó ogun jọ lẹ́bá a oríṣun Háṣódì. Àwọn ogun Mídíánì sì wà ní apá àríwá tí wọ́n ní àfonífojì tí ó wà ní ẹ̀bá òkè Mórè.

Ka pipe ipin Onídájọ́ 7

Wo Onídájọ́ 7:1 ni o tọ