Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Onídájọ́ 4:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bárákì àti àwọn ogun rẹ̀ sì lé àwọn ọ̀tá náà, àwọn ọmọ ogun orílẹ̀ àti àwọn kẹ̀kẹ́ ogun wọn títí dé Háróṣétì ti àwọn orílẹ̀ èdè, títí ó fi pa gbogbo àwọn ọmọ ogun Ṣísérà kò sí ọ̀kan tí ó lè sálà tàbí tí ó wà láàyè.

Ka pipe ipin Onídájọ́ 4

Wo Onídájọ́ 4:16 ni o tọ