Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Onídájọ́ 4:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa sì mú ìdàrúdàpọ̀ wá sí àárin ogun Sísérà, Olúwa sì fi ojú idà ṣẹ́gun Sísérà àti àwọn oníkẹ̀kẹ́ ogun àti ọmọ ogun orí ilẹ̀ ní iwájú Bárákì. Sísérà sì sọ̀kalẹ̀ lórí kẹ̀kẹ́ ogun rẹ̀ ó sì fi ẹṣẹ̀ sálọ.

Ka pipe ipin Onídájọ́ 4

Wo Onídájọ́ 4:15 ni o tọ