Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Onídájọ́ 20:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

(Àwọn ẹ̀yà Bẹ́ńjámínì gbọ́ wí pé àwọn ọmọ Ísírẹ́lì yóòkù ti gòkè lọ sí Mísípà). Nígbà náà ni àwọn ọmọ Ísírẹ́lì wí pé, “Ẹ sọ fún wa báwo ni iṣẹ́ búburú ṣe ṣẹlẹ̀.”

Ka pipe ipin Onídájọ́ 20

Wo Onídájọ́ 20:3 ni o tọ