Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Onídájọ́ 20:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn olórí gbogbo àwọn ènìyàn láti gbogbo ẹ̀yà Ísírẹ́lì dúró ní ipò wọn ní àpèjọ àwọn ènìyàn Ọlọ́run, ogún ọ̀kẹ́ ọkùnrin ológun ti àwọn àti idà wọn.

Ka pipe ipin Onídájọ́ 20

Wo Onídájọ́ 20:2 ni o tọ