Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Onídájọ́ 20:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ọjọ́ yìí nígbà tí ará Bẹ́ńjámínì jáde sí wọn láti Gíbíà, láti dojú kọ wọn, wọ́n pa ẹgbẹ̀sán (18,000) ọkùnrin Ísírẹ́lì, gbogbo wọn jẹ́ jagunjagun tí ń lo idà.

Ka pipe ipin Onídájọ́ 20

Wo Onídájọ́ 20:25 ni o tọ