(Àwọn òbí rẹ̀ kò mọ̀ pé ọ̀dọ̀ Olúwa ni nǹkan yìí ti wá, ẹni tí ń wá ọ̀nà àti bá Fílístínì jà; nítorí àwọn ni ń ṣe àkóso Ísírẹ́lì ní àkókò náà.)