Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Onídájọ́ 14:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Sámúsónì sọ̀kalẹ̀ lọ sí Tímínà òun àti bàbá àti ìyá rẹ̀. Bí wọ́n ṣe ń súnmọ́ àwọn ọgbà àjàrà tí ó wà ní Tímínà, láìrò tẹ́lẹ̀, ọ̀dọ́ kìnnìún kan jáde síta tí ń ké ramúramù bọ̀ wá sí ọ̀dọ̀ rẹ̀.

Ka pipe ipin Onídájọ́ 14

Wo Onídájọ́ 14:5 ni o tọ