Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Onídájọ́ 12:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

wọ́n ó wí fún un pé, “Ó dá à wí pé ‘Ṣhíbólétì.’ ” Tí ó bá ní, “Síbólé,” tì torí pé kò ní mọ̀ọ́ pé dáadáa, wọ́n á mú-un wọn, a sì pa á ni àbáwọdò Jọ́dánì. Àwọn ará Éfúráímù tí wọn pa ní àkókò yìí jẹ́ ẹgbẹ̀rún méjìléní-ogójì ọkùnrin.

Ka pipe ipin Onídájọ́ 12

Wo Onídájọ́ 12:6 ni o tọ